Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 17:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo igi inu igbẹ ni yio si mọ̀ pe, emi Oluwa li o ti mu igi giga walẹ, ti mo ti gbe igi rirẹlẹ soke, ti mo ti mu igi tutù gbẹ, ti mo si ti mu igi gbigbẹ ruwé: emi Oluwa li o ti sọ ti mo si ti ṣe e.

Ka pipe ipin Esek 17

Wo Esek 17:24 ni o tọ