Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati mo si kọja lọdọ rẹ, ti mo si wò ọ; kiye si i, ìgba rẹ jẹ ìgba ifẹ; mo si nà aṣọ mi bò ọ, mo si bo ihoho rẹ: nitõtọ, mo bura fun ọ, mo si ba ọ da majẹmu, ni Oluwa Ọlọrun wi, iwọ si di temi.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:8 ni o tọ