Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:63 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o le ranti, ki o si le dãmu, ki iwọ ki o má si le yà ẹnu rẹ mọ nitori itiju rẹ, nigbati inu mi ba tutù si ọ, nitori ohun ti iwọ ti ṣe, ni Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:63 ni o tọ