Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati mo si kọja lọdọ rẹ, ti mo si ri ọ, ti a tẹ̀ ọ mọlẹ ninu ẹjẹ ara rẹ, mo wi fun ọ nigbati iwọ wà ninu ẹjẹ rẹ pe, Yè: nitõtọ, mo wi fun ọ nigbati iwọ wà ninu ẹjẹ rẹ pe, Yè.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:6 ni o tọ