Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ pẹlu, ti o ti da awọn arabinrin rẹ lẹbi, ru itiju ara rẹ, nitori ẹ̀ṣẹ rẹ ti iwọ ti ṣe ni iṣe irira jù wọn lọ: awọn ṣe olododo jù iwọ lọ; nitotọ, ki iwọ ki o dãmu pẹlu, si ru itiju rẹ, nitipe iwọ dá awọn arabinrin rẹ lare.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:52 ni o tọ