Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati niti ìbi rẹ, a kò da ọ ni iwọ́ ni ijọ ti a bi ọ, bẹ̃ni a kò wẹ̀ ọ ninu omi lati mu ọ mọ́, a kò fi iyọ̀ pa ọ lara rara, bẹ̃ni a kò fi ọja wé ọ rara.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:4 ni o tọ