Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni a fi wura ati fadaka ṣe ọ lọṣọ; aṣọ rẹ si jẹ ọgbọ̀ daradara, ati ṣẹ́dà, ati aṣọ oniṣẹ-ọnà; iwọ jẹ iyẹfun daradara ati oyin, ati ororo: iwọ si ni ẹwà gidigidi, iwọ si gbilẹ di ijọba kan.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:13 ni o tọ