Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi a ba si tan wolĩ na jẹ nigbati o sọ ohun kan, Emi Oluwa ni mo ti tan wolĩ na jẹ, emi o si nawọ mi le e, emi o si run u kuro lãrin Israeli enia mi.

Ka pipe ipin Esek 14

Wo Esek 14:9 ni o tọ