Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 13:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Nitori ẹnyin ti sọ̀rọ asan, ẹnyin si ti ri eke, nitorina, kiyesi i, mo dojukọ nyin, ni Oluwa wi.

Ka pipe ipin Esek 13

Wo Esek 13:8 ni o tọ