Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 12:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, iwọ ọmọ enia, mura nkan kikolọ, ki o si kó lọ li oju wọn li ọsan; ki o si kó lati ipò rẹ lọ si ibomiran li oju wọn; o le ṣe pe nwọn o ronu, bi nwọn tilẹ jẹ ọlọ̀tẹ ile.

Ka pipe ipin Esek 12

Wo Esek 12:3 ni o tọ