Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 11:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun wi, Awọn okú nyin ti ẹnyin ti tẹ́ si ãrin rẹ̀, awọn ni ẹran, ilu yi si ni ìgba; ṣugbọn emi o mu nyin jade kuro lãrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 11

Wo Esek 11:7 ni o tọ