Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 11:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹmi Oluwa si bà le mi, o si wi fun mi pe, Sọ̀rọ; Bayi li Oluwa wi; Bayi li ẹnyin ti wi, Ile Israeli, nitoriti mo mọ̀ olukuluku ohun ti o wá si inu nyin.

Ka pipe ipin Esek 11

Wo Esek 11:5 ni o tọ