Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 10:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati o ti paṣẹ fun ọkunrin ti o wọ aṣọ ọgbọ, wipe, Fọn iná lati ãrin awọn kẹkẹ, lati ãrin awọn kerubu, o si wọ inu ile, o si duro lẹba awọn kẹkẹ.

Ka pipe ipin Esek 10

Wo Esek 10:6 ni o tọ