Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 10:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sọ fun ọkunrin ti o wọ aṣọ ọ̀gbọ, o si wipe, Bọ sarin kẹkẹ, labẹ kerubu; si bu ikúnwọ ẹyin iná lati agbedemeji awọn kerubu; si fọ́n wọn ka sori ilu na. O si wọ inu ile li oju mi.

Ka pipe ipin Esek 10

Wo Esek 10:2 ni o tọ