Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 10:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn kerubu si gbe iyẹ́ wọn soke, nwọn si fò kuro lori ilẹ li oju mi: nigbati nwọn jade lọ, awọn kẹkẹ wà li ẹgbẹ̀ wọn pẹlu, olukuluku si duro nibi ilẹkun ẹnu-ọ̀na ilà-õrun ile Oluwa: ogo Ọlọrun Israeli si wà lori wọn loke.

Ka pipe ipin Esek 10

Wo Esek 10:19 ni o tọ