Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 1:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si ri bi awọ amberi, bi irí iná yika ninu rẹ̀, lati irí ẹgbẹ́ rẹ̀ de oke, ati lati irí ẹgbẹ́ rẹ̀ de isalẹ, mo ri bi ẹnipe irí iná, o si ni didan yika.

Ka pipe ipin Esek 1

Wo Esek 1:27 ni o tọ