Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 8:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si sọ fun Mose pe, Wi fun Aaroni pe, Nà ọwọ́ rẹ pẹlu ọpá rẹ sori odò wọnni, sori omi ṣiṣàn, ati sori ikojọpọ̀ omi, ki o si mú ọpọlọ jade wá sori ilẹ Egipti.

Ka pipe ipin Eks 8

Wo Eks 8:5 ni o tọ