Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 8:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao si wipe, Emi o jẹ ki ẹnyin lọ, ki ẹ le rubọ si OLUWA Ọlọrun nyin ni ijù; kìki ki ẹnyin ki o máṣe lọ jìna jù: ẹ bẹ̀bẹ fun mi.

Ka pipe ipin Eks 8

Wo Eks 8:28 ni o tọ