Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 8:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si wipe, Kò tọ́ lati ṣe bẹ̃; nitori awa o fi ohun irira awọn ara Egipti rubọ si OLUWA Ọlọrun wa: wò o, awa le fi ohun irira awọn ara Egipti rubọ li oju wọn, nwọn ki yio ha sọ wa li okuta?

Ka pipe ipin Eks 8

Wo Eks 8:26 ni o tọ