Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 8:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si ṣe bẹ̃; ọwọ́ eṣinṣin ọ̀pọlọpọ si dé sinu ile Farao, ati sinu ile awọn iranṣẹ rẹ̀: ati ni gbogbo ilẹ Egipti, ilẹ na bàjẹ́ nitori ọwọ́ eṣinṣin wọnni.

Ka pipe ipin Eks 8

Wo Eks 8:24 ni o tọ