Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 7:23-25 Yorùbá Bibeli (YCE)

23. Farao si pada o lọ si ile rẹ̀, kò si fi ọkàn rẹ̀ si eyi pẹlu.

24. Gbogbo awọn ara Egipti si wàlẹ yi odò na ká fun omi mimu; nitoriti nwọn kò le mu ninu omi na.

25. Ọjọ́ meje si pé, lẹhin igbati OLUWA lù odò na.

Ka pipe ipin Eks 7