Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 5:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao si wipe, Tali OLUWA, ti emi o fi gbà ohùn rẹ̀ gbọ́ lati jẹ ki Israeli ki o lọ? Emi kò mọ̀ OLUWA na, bẹ̃li emi ki yio jẹ ki Israeli ki o lọ.

Ka pipe ipin Eks 5

Wo Eks 5:2 ni o tọ