Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 4:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Sippora mú okuta mimú, o si kọ ọmọ rẹ̀ ni ilà abẹ, o si sọ ọ si ẹsẹ̀ Mose, o si wipe, Ọkọ ẹlẹjẹ ni iwọ fun mi nitõtọ.

Ka pipe ipin Eks 4

Wo Eks 4:25 ni o tọ