Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 35:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wá, olukuluku ẹniti ọkàn rẹ́ ru ninu rẹ̀, ati olukuluku ẹniti ọkàn rẹ̀ mu u fẹ́, nwọn si mú ọrẹ OLUWA wá fun iṣẹ agọ́ ajọ na, ati fun ìsin rẹ̀ gbogbo, ati fun aṣọ mimọ́ wọnni.

Ka pipe ipin Eks 35

Wo Eks 35:21 ni o tọ