Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 35:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ijọ́ mẹfa ni ki a fi ṣe iṣẹ, ṣugbọn ijọ́ keje ni yio ṣe ọjọ́ mimọ́ fun nyin, ọjọ́ isimi ọ̀wọ si OLUWA: ẹnikẹni ti o ba ṣe iṣẹ ninu rẹ̀ li a o lupa nitõtọ.

Ka pipe ipin Eks 35

Wo Eks 35:2 ni o tọ