Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si gbẹ́ walã okuta meji bi ti iṣaju; Mose si dide ni kutukutu owurọ̀, o si gún òke Sinai, bi OLUWA ti paṣẹ fun u, o si mú walã okuta mejeji li ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:4 ni o tọ