Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wà nibẹ̀, lọdọ OLUWA li ogoji ọsán ati ogoji oru: on kò jẹ onjẹ, bẹ̃ni kò mu omi. On si kọwe ọ̀rọ majẹmu na, ofin mẹwa nì, sara walã wọnni.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:28 ni o tọ