Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o má si ṣe fẹ́ ninu awọn ọmọbinrin wọn fun awọn ọmokọnrin rẹ, ki awọn ọmọbinrin wọn ki o má ba ṣe àgbere tọ̀ oriṣa wọn, ki nwọn ki o má ba mu ki awọn ọmọkunrin rẹ ki o ṣe àgbere tọ̀ oriṣa wọn.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:16 ni o tọ