Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Kiyesi i, emi dá majẹmu kan: emi o ṣe ohun iyanu, niwaju gbogbo awọn enia rẹ irú eyiti a kò ti iṣe lori ilẹ gbogbo rí, ati ninu gbogbo orilẹ-ède: ati gbogbo enia ninu awọn ti iwọ wà, nwọn o ri iṣẹ OLUWA, nitori ohun ẹ̀ru li emi o fi ọ ṣe.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:10 ni o tọ