Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 33:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi Mose ti dé ibi agọ́ na, ọwọ̀n awọsanma sọkalẹ, o si duro li ẹnu-ọ̀na agọ́ na: OLUWA si bá Mose sọ̀rọ.

Ka pipe ipin Eks 33

Wo Eks 33:9 ni o tọ