Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 33:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nipa ewo li a o fi mọ̀ nihinyi pe, emi ri ore-ọfẹ li oju rẹ, ani emi ati awọn enia rẹ? ki iha iṣe ni ti pe iwọ mbá wa lọ ni, bẹ̃ni a o si yà wa sọ̀tọ, emi ati awọn enia rẹ, kuro lara gbogbo enia ti o wà lori ilẹ?

Ka pipe ipin Eks 33

Wo Eks 33:16 ni o tọ