Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 30:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati oruka wurà meji ni ki iwọ ki o ṣe nisalẹ igbáti rẹ̀, ni ìha igun rẹ̀ meji, li ẹgbẹ rẹ̀ mejeji ni ki iwọ ki o ṣe e si; nwọn o si jasi ipò fun ọpá wọnni, lati ma fi gbé e.

Ka pipe ipin Eks 30

Wo Eks 30:4 ni o tọ