Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 26:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe aṣọ-tita kan fun ẹnu-ọ̀na agọ́ na, ti aṣọ-alaró, ti elesè-aluko, ti ododó, ati ti ọ̀gbọ olokùn wiwẹ, ti a fi iṣẹ abẹ́rẹ ṣe.

Ka pipe ipin Eks 26

Wo Eks 26:36 ni o tọ