Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 26:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si fi wurà bò apáko wọnni, iwọ o si fi wurà ṣe oruka wọn li àye fun ọpá idabu wọnni: iwọ o si fi wurà bò ọpá idabu wọnni.

Ka pipe ipin Eks 26

Wo Eks 26:29 ni o tọ