Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 26:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si jẹ́ apáko mẹjọ, ati ihò-ìtẹbọ fadakà wọn, ihò-ìtẹbọ mẹrindilogun; ihò-ìtẹbọ meji nisalẹ apáko kan, ati ihò-ìtẹbọ meji nisalẹ apáko keji.

Ka pipe ipin Eks 26

Wo Eks 26:25 ni o tọ