Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 24:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun awọn àgba na pe, Ẹ duro dè wa nihinyi, titi awa o fi tun pada tọ̀ nyin wá: si kiyesi i, Aaroni ati Huri mbẹ pẹlu nyin: bi ẹnikan ba li ọ̀ran kan, ki o tọ̀ wọn wá.

Ka pipe ipin Eks 24

Wo Eks 24:14 ni o tọ