Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 24:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Gòke tọ̀ mi wá sori òke, ki o si duro nibẹ̀; emi o si fi walã okuta fun ọ, ati aṣẹ kan, ati ofin ti mo ti kọ, ki iwọ ki o le ma kọ́ wọn.

Ka pipe ipin Eks 24

Wo Eks 24:12 ni o tọ