Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 23:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Akọ́ka eso ilẹ rẹ ni ki iwọ ki o múwa si ile OLUWA Ọlọrun rẹ. Iwọ kò gbọdọ bọ̀ ọmọ ewurẹ ninu warà iya rẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 23

Wo Eks 23:19 ni o tọ