Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 23:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ijọ́ mẹfa ni iwọ o ṣe iṣẹ rẹ, ni ijọ́ keje ki iwọ ki o si simi: ki akọmalu rẹ, ati kẹtẹkẹtẹ rẹ ki o le simi, ki a le tù ọmọ iranṣẹbinrin rẹ, ati alejò, lara.

Ka pipe ipin Eks 23

Wo Eks 23:12 ni o tọ