Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 22:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iná ba ṣẹ̀, ti o si mu ẹwọn, ti abà ọkà, tabi ọkà aiṣá, tabi oko li o joná; ẹniti o ràn iná na yio san ẹsan nitõtọ.

Ka pipe ipin Eks 22

Wo Eks 22:6 ni o tọ