Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 22:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori kìki eyi ni ibora rẹ̀, aṣọ rẹ̀ ti yio fi bora ni: kini on o fi bora sùn? yio si ṣe bi o ba kigbe pè mi, emi o gbọ́; nitori alãnu li emi.

Ka pipe ipin Eks 22

Wo Eks 22:27 ni o tọ