Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 20:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ kò gbọdọ yá ere fun ara rẹ, tabi aworan ohun kan ti mbẹ loke ọrun, tabi ti ohun kan ti mbẹ ni isalẹ ilẹ, tabi ti ohun kan ti mbẹ ninu omi ni isalẹ̀ ilẹ.

Ka pipe ipin Eks 20

Wo Eks 20:4 ni o tọ