Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọbinrin Farao si wi fun u pe, Gbé ọmọ yi lọ ki o si tọ́ ọ fun mi, emi o si san owo iṣẹ rẹ fun ọ. Obinrin na si gbé ọmọ na lọ, o si tọ́ ọ.

Ka pipe ipin Eks 2

Wo Eks 2:9 ni o tọ