Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọbinrin Farao si sọkalẹ wá lati wẹ̀ li odò; awọn ọmọbinrin ọdọ rẹ̀ si nrìn lọ li ẹba odò na; nigbati o si ri apoti na lãrin koriko odò, o rán ọmọbinrin ọdọ rẹ̀ kan lati lọ gbé e wá.

Ka pipe ipin Eks 2

Wo Eks 2:5 ni o tọ