Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wò ihin, o wò ọhún, nigbati o si ri pe, kò si ẹnikan, o lù ara Egipti na pa, o si bò o ninu yanrin.

Ka pipe ipin Eks 2

Wo Eks 2:12 ni o tọ