Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 17:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li awọn enia na ṣe mbá Mose sọ̀, nwọn si wipe, Fun wa li omi ki a mu. Mose si wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi mbà mi sọ̀? ẽṣe ti ẹnyin fi ndán OLUWA wò?

Ka pipe ipin Eks 17

Wo Eks 17:2 ni o tọ