Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 17:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọwọ́ kún Mose; nwọn si mú okuta kan, nwọn si fi si abẹ rẹ̀, o si joko lé e; Aaroni ati Huri si mu u li ọwọ́ ró, ọkan li apa kini, ekeji li apa keji; ọwọ́ rẹ̀ si duro gan titi o fi di ìwọ-õrùn.

Ka pipe ipin Eks 17

Wo Eks 17:12 ni o tọ