Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 16:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li OLUWA sọ fun Mose pe, Kiyesi i, emi o rọ̀jo onjẹ fun nyin lati ọrun wá; awọn enia yio si ma jade lọ ikó ìwọn ti õjọ li ojojumọ́, ki emi ki o le dan wọn wò, bi nwọn o fẹ́ lati ma rìn nipa ofin mi, bi bẹ̃kọ.

Ka pipe ipin Eks 16

Wo Eks 16:4 ni o tọ