Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 16:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ọmọ Israeli si ri i, nwọn wi fun ara wọn pe, Kili eyi? nitoriti nwọn kò mọ̀ ohun na. Mose si wi fun wọn pe, Eyi li onjẹ ti OLUWA fi fun nyin lati jẹ.

Ka pipe ipin Eks 16

Wo Eks 16:15 ni o tọ