Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 16:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NWỌN si ṣí lati Elimu, gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli si dé ijù Sini, ti o wà li agbedemeji Elimu on Sinai, ni ijọ́ kẹdogun oṣù keji, lẹhin igbati nwọn jade kuro ni ilẹ Egipti.

Ka pipe ipin Eks 16

Wo Eks 16:1 ni o tọ